ASTRONOMY AND GEOGRAPHY IN YORUBA
Earth – Aye
Cloud – Ikuuku
Rain – Ojo, Eji
Storm – Iji
Sirius – Irawọ alẹ
Sea – Okun
Open water – Agbami
Ocean – Agbami Okun
Rock – Apata
Lagoon – Ọsa
Waterfall – Oṣọrọ
Lightening – Mọnamọna
Venus – Àgùàlà, Aja oṣu
Moon – Oṣu, Oṣupa
Sun – Oorun
Peak – Tente, Ṣonṣo, Gongo
Stars – Irawọ
Land – Ilẹ
Fog – Kùrukùru
Planet – Isọgbe oorun
Wave/Surf – Igbi
Dust storm – Ebutu, Eruku, Ẹbu
Dawn – Afẹmọju, Ojumọ
Dusk – Aṣalẹ
Realm/Domain – Orilẹ
Eclipse – Iṣijibo
Earthquake – Ọmimi Ilẹ, Isẹlẹ
Dyke/Bank – Bebe
Gale, Tempest – Ẹfuufu
Thunder – Apaara, Ara
Air – Atẹgun
Wind/Breeze – Afẹfẹ
Valley – Ijigọnrọn, Ipẹtẹlẹ
Field – Papa
Island – Erekuṣu, Adado
Mountain – Oke
Brook – Oteere, Oterere
Hill/Hillock – Okiti
Whirlwind/Tornado – Aaja
Spring/Fountain – Ṣẹlẹru
Crust – Eepa ilẹ
Desert – Aṣalẹ
Spume/foam – Eefó
Gully/Ditch – Iyara
Universe – Agbaye
Coast – Etikun
Pit – Iho, Ọfin
Boundary – Ibode
Border – Aala
Sandstone/Laterite – Yangi
Torrent – Àgbàrá
New moon/Crescent – Oṣule
Full moon – Aranmoju
Pool – Ọgọdọ
Cliff – Ẹbìtì
North pole – Igun ariwa
South pole – Igun guusu
Flood – Ẹkun omi, Omiyale
Phenomenon – Àdìtú
Harmattan – Ọyẹ
Bush/Woods – Igbo, Igbẹ
Forest – Ẹgan
Pond – Abata
Savanna/Plain – Ọdan
Grove – Igbalẹ, Oṣuṣu
Rainbow – Oṣumare
Ravine – Afonifoji
River – Odo, Ẹri
Lake – Adagun
Drought – Ọdá
Comet – Irawọ abiru/oniru
Famine – Iyan, Ọgbẹlẹ
Mineral – Kùsà
Tide – Ọsa, Iṣa
Rays – Titanṣaan
Dew – Iri
Seasson – Asiko
Ice/Hailstone – Yinyin
Dusk – Aṣalẹ
Plateau – Pẹtẹlẹ
Colony/Dependency – Ereko
Altitude – Ìga
Wilderness – Aginju
Humidity – Ọrinrin
Shower – Ọwara
Swamp/Marsh – Ẹrẹ, Ira
Harbour – Ebute
Abyss – Ọgbun
Atmosphere/Void – Ofurufu
Slope – Idagẹẹrẹ, Gẹẹrẹ
#ogunupdate