&

Barr. Chf. Mrs. Oluwatoyin Abegunde

& ()
Jatropha – Lapa Lapa
Ricinodendron – Erinmado
Sorghum – Ọkababa, Poroporo
Quinine – Ọra ojola
Myrrh – Ojia
Cloves – Kanafuru
Asthma Weed – Emi ile, Iroko iju, Egele
Celosia – Marugbo, Ajẹmawofo, Ajẹfọwo, Gbanunu
Hogweed – Etipọnla
Goosefoot – Arunpale
Canthium – Ajelora
Fleabane – Olowojẹja
Lagos Spinach – Ẹfọ sọkọyọkọtọ
Gliricidia – Agunmaniye
Moringa – Ewelẹ, Adagbamalero
Frankincense – Igi Turari
Bitter/Yellow Yam – Iṣu esuru
Cactus – Oro adẹtẹ
False Nutmeg – Akomu
Pearl millet – Jero, Emeye
Water Yam – Iṣu ewura
Goat Weed – Imi Esu
Yohimbe – Idagbọn (Burantashi in Hausa)
Resurrection/Miracle plant – Abamoda
Crab’s eye/Rosary pea – Oju ologbo/Omisinmisin
Sand paper fig – Eepin
Kigelia (Sausage tree) – Pandoro
Luffa – Erun
Lettuce – Ẹfọ yanrin oko
Mahogany – Ọganwo, Apa
Camel foot – Abefe
Oleander – Adodo
Calabash nutmeg – Sasangbaku
Brimstone tree (Morinda) – Oruwo
Jack Bean – Sese
African peach – Egbẹsi
Velvet Bean/Cow itch – Werepe, Esisi, Yerepe
Jatropha / Ricinodendron – Erinmado
Macaranga – Asasa, Agbaasa
Boundary Tree/Tree of Life – Akoko
African Crabwood – Ọganwo
African Mustard/Fig – Ọpọtọ
Creeping Foxglove (Senegal tea) – Lobiiri
Henna – Laali
Thorny green Amaranth – Tete ẹlẹgun
Joyweed Amaranth – Dagunro
Prickly Amaranth – Reku reku
Marsh Barbel – Ogbigbo
Mountain Knotgrass – Ẹfun ilẹ
Uraria – Alupayida
Olene Irvingia – Karakoro
Custard Apple – Abo, Ibobo
Mexican Poppy – Egun arugbo
Mock Tomato/Scarlet Eggplant – Efọ gbagba
Milkweed (Sodom Apple) – Bomubomu
Asparagus – Aluki
Breadfruit – Àfọ̀n
Adenia – Arokeke, Godogbo
Green Amaranth – Tẹtẹ abalaye
Pepper Elder – Ẹfọ rinrin
Trellis Vine – Kolerọgba / Ewe atufa
Devill’s Fig – Mafọwọkanmọ
Caloncoba – Kakandika
Jollyanum – Akerejupọn
Mistletoe – Afomọ
Tree Marigold – Jogbo
Elephant Grass – Ẹsun
Uvaria Banana – Eruju
Guinea Peper (Grain of Selim) – Eeru
Indian Goosegrass – Gbagi
Alewood – Ayin
Yoruba Soft Cane – Ewe iran
African Crocus (Pilosa) – Epakun
Bermuda grass – Koriko bamubu
African Pear – Elemi (Ube in igbo)
Eveuss – Kanakoru
Velvet Leaf (Cissampelos) – Ewe jokoje
Cardamom – Oburọ
Bush mango (Irvingia) – Oro
Sword lily – Baka
Coco Yam – Iṣu koko
White Yam – Iṣu Igo
Aerial/Bulb Yam – Iṣu emina
Baobab – Oṣe
Fiji Arrowroot – Iṣu ado (Adoṣu)
Marigold – Ododo maria
Congo Jute – Ilasa agborin
Horse Tamarind – Esura
Alafia chewing stick – Agbari ẹtu
Wild groundnut (Calopo) – Apalofa
Aloe Vera – Eti erin, Ida egungun
African false currant – Eekana ehoro
False Iroko – Oriro, Ooro
Camwood – Irosun, Osun
Hogweed – Etiponla
Black Mangrove – Ogbun
Sword Bean – Popondo, Sese nla
Fever nut – Ayoo
Adamant Creeper – OgbakiikiBurkea – Apasa
Shea butter tree – Emi emi
Pride of Barbados – Ẹkọ ọmọde
Heart of Jesus plant – Ẹjẹ Jesu
African arrowroot – Idodo
Small-leaved Dragon Tree – Peregun
Caper Bush (humbug tree) – Eekana awodi, Ẹwọn ẹkiri
Castor Bean – Laarà
African Crabwood – Irere, Abo Ọganwo
Balloon vine – ShaworoInk Plant/False Daisy – Abikole
Devil’s gut – Ọmọnigelegele
Cattle stick, Poorman’s candle – Oshunshun
Rose Periwinkle – Apabida pupa
Silk Cotton tree/Kapok – Araba
Bittersweet plant – Pọnju owiwi, Iṣẹpolohun
Bull’s-eye Seed – Agbaarin
Natal Elm/White Stinkwood – Ita gidi, Ewon agogo
Jesuit’s Tea – Ewe arunpale, Ewe imi
Indian Chrysanths – Abilere
Clausena – Agbari obukọ
Diamond Flower/Oldelandia – Oyigi
African Cordia – Ọmọ
Credit: YorubNationCH on Twitr

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

You cannot copy content of this page